Oju ewe kinni
Nipa Websusaiti yi
Darapo mo wa
E kansi wa
Nipa AFÁRÁ

 

Wa nkan pelu AltaVista

Talo fe Yahoo?

Eleyi o gbe e lo si yahoo mail

 Awn Owe Yoruba

Awon linki pataki

Paradigm Initiative Nigeria
GbengaSesan
Nigeria Tommorrow
Obafemi Awolowo Univ.
Oro lori Afara yi
 
Deeti:
  Ole j wipe igba akk ti n de website yi niyi. E kaab lakansi.
Eyi ni oju ewe ak
k to mission Yoruba .8m.com. Mission Yoruba j website ti a fi ede Yoruba k lati oke titi de isal. E ma je ki o ya yin lnu o, apẹẹr ni eleyii j lati fi han wipe plu gbn ati oye ti o wa ni il Nigeria, a le k afara ti yio di alafo ti o wa laarin Africa ati il oke okun (apẹẹre bi America ati Europe).

Ti a ba wo orile ede wa Nigeria leni a o ri wipe opolopo nnkan ni a le se fun ara wa laisi ani ani.Fun apeere Omo Nigeria kan ni o dani kan se ero ayara bi asa-computer eyi ti o yara julo ni odun 1989.Eni ti a nsoro re yi ni Philip emeagwali.Omo bibi ile wa ni,ki o to lo si ile America nigba ogun abele ti Biafra.E le ka nipa Emeagwali ni www.emeagwali.com.

Loni a o ri wipe Ile wa Nigeria ko le ta putu laarin awon ilu bi America, Japan tabi Britain. Paapajulo ni awon ona ti o je mo ti lilo ero ayara bi asa lati fi fun ilu ni awo ti o dara. Fun apeere,oro tio so sini lenu tio si buyo si ni wipe ti a ba ro gbogbo awon ero ayara bi asa computer ti o wa ni gbogbo ile Africa papo,ko ti to awon eyi tio wa ni ile America nikan soso! sibe sibe,baba nla oto oro ni.

Siwaju si, opolopo eniyan nile Oke okun lo mo nipa ero ayara bi asa- computer,beeni amoye si nii sile,amo ni Nigeria loni, eniyan melo lo  mo nnkan tio je computer a ba le tasi ki o nii sile.

Ninu gbogbo siso, a o ri wipe, eleyi ti da alafo nla kan si aarin Africa ati awon ilu okere.Alafo nla yi ni won npe ni 'Digital divide ' ni ede geesi.

Amo o je nnkan ayo lati mo pe orisirisi ona ni opolopo awon eniyan jankan jankan nilu yi ti n wa lati ri wipe afara kan je kiko. Afara yi ni yio je ki ona wa fun Africa lati bori alafo yi .Aanfani nla nla ni eleyi yio se fun Africa ti o ti wa leyin fun odun pipe. 

 

 
©copyright 2003 Popoola Edward Olayemi

Oju ewe akoko | Nipa website yi | Dara po mo wa | E kansi wa